Yoruba Numbers

YORÙBÁ
ÒǸKÀ YORÙBÁ

1– ọ̀kan/ení

2– m éjì

3– m ẹ́ta

4 – m ẹ́rin

5 – m árùn ún

6 – m ẹ́fà

7 – m éje

8 – m ẹ́jọ

9 – m ẹ́sán án

10 – m ẹ́wàá

11 – mọ̀kànlá

12 – méjìlá

13 – mẹ́tàlá

14 – mẹ́rìnlá

15 = màrúndínlógún

16 = mẹ́rìndínlógún

17 = mẹ́tàdínlógún

18 = méjìdínlógún

19 = mọ́kàndínlógún

20 = ogún

21 = mọ́kànlélógún

22 = méjìlélógún

23 = mẹ́tàlélógún

24 = mẹ́rìnlélógún

25 = márùndínlọ́gbọ̀n

26 = mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n

27 = mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n

28 = méjídínlọ́gbọ̀n

29 = mọ́kàndínlọ́gbọ̀n

30 = ọgbọ̀n

31 = mọ́kànlélọ́gbọ̀n

32 = méjílélọ́gbọ̀n

33 = mẹ́tàlélọ́gbọ̀n

34 = mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n

35= márùndínlógójì

36= mẹ́rìndínlógójì

37= mẹ́tàdínlógójì

38= méjídínlógójì

39= mọ́kàndínlógójì

40 = ogójì

41 = mọ́kànlélógójì

42 = méjílélógójì

43 = mẹ́tàlélógójì

44 = mẹ́rìnlélógójì

45= márùndínláàdọ́ta

46= mẹ́rìndínláàdọ́ta

47= mẹ́tàdínláàdọ́ta

48= méjídínláàdọ́ta

49= mọ́kàndínláàdọ́ta

50= àádọ́ta

51= mọ́kànléláàdọ́ta

52 = méjílélógójì

53 = mẹ́tàlélógójì

54 = mẹ́rìnlélógójì

55= márùndínlọ́gọ́ta

56= mẹ́rìndínllọ́gọ́ta

57= mẹ́tàdínllọ́gọ́ta

58= méjídínllọ́gọ́ta

59= mọ́kàndínlọ́gọ́ta

60= ọgọ́ta

61= mọ́kànlélọ́gọ́ta

62 = méjílélọ́gọ́ta

63 = mẹ́tàlélọ́gọ́ta

64 = mẹ́rìnlélọ́gọ́ta

65= márùndínláàdọ́rin

66= mẹ́rìndínláàdọ́rin

67= mẹ́tàdínláàdọ́rin

68= méjídínláàdọ́rin

69= mọ́kàndínláàdọ́rin

70= àádọ́rin

71= mọ́kànléláàdọ́rin

72 = méjíléláàdọ́rin

73 = mẹ́tàléláàdọ́rin

74 = mẹ́rìnléláàdọ́rin

75= márùndínlọ́gọ́rin

76= mẹ́rìndínlọ́gọ́rin

77= mẹ́tàdínlọ́gọ́rin

78= méjídínlọ́gọ́rin

79= mọ́kàndínlọ́gọ́rin

80= ọgọ́rin

81= mọ́kànlélọ́gọ́rin

82 = méjílélọ́gọ́rin

83 = mẹ́tàlélọ́gọ́rin

84 = mẹ́rìnlélọ́gọ́rin

85= márùndínláàdọ́rùn ún

86= mẹ́rìndínláàdọ́rùn ún

87= mẹ́tàdínláàdọ́rùn ún

88= méjídínláàdọ́rùn ún

89= mọ́kàndínláàdọ́rùn ún

90= àádọ̀rún

91= mọ́kànléláàdọ́rùn ún

92= méjìléláàdọ́rùn ún

93= mẹ́tàléláàdọ́rùn ún

94= mẹ́rìnléláàdọ́rùn ún

95= màrúndínlọ́gọ́rùn ún

96= mẹ́rìndínlọ́gọ́rùn ún

97= mẹ́tàdínlọ́gọ́rùn ún

98= méjídínlọ́gọ́rùn ún

99= mọ́kàndínlọ́gọ́rùn ún

100= ọgọ́rùn ún

400 = irinwó

500 = ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta

600 = ẹgbẹ̀ta

700 = ẹ̀ẹ́dẹ̀gbẹ̀rin

800 = ẹgbẹ̀rin

900 = ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárun

1000 = ẹ̀gbẹ̀rún

101 = mọ́kànlélọ́gọ́rùn ún

102= méjìlélọ́gọ́rùn ún

103= mẹ́tàlélọ́gọ́rùn ún

104= mẹ́rìnlélọ́gọ́rùn ún

105= márùndínláàdọ́fà

106= mẹ́rìndínláàdọ́fà

107= mẹ́tàdínláàdọ́fà

108= méjìdínláàdọ́fà

109= mọ́kàndínláàdọ́fà

110= àádọ́fà

111 = mọ́kànléláàdọ́fà

112= méjìléláàdọ́fà

113= mẹ́tàléláàdọ́fà

114= mẹ́rìnléláàdọ́fà

115= márùndínlọ́gọ́fà

116= mẹ́rìndínlọ́gọ́fà

117= mẹ́tàdínlọ́gọ́fà

118= méjídínlọ́gọ́fà

119= mọ́kàndínlọ́gọ́fà

120= ọgọ́fà

121 = mọ́kànlélọ́gọ́fà

122= méjìlélọ́gọ́fà

123= mẹ́tàlélọ́gọ́fà

124= mẹ́rìnlélọ́gọ́fà

125= márùndínláàdóje

126= mẹ́rìndínláàdóje

127= mẹ́tàdínláàdóje

128= méjìdínláàdóje

129= mọ́kàndínláàdọ́fà

130= àádóje

131 = mọ́kànlélàádóje

132= méjìlélàádóje

133= mẹ́tàlélàádóje

134= mẹ́rìnlélàádóje

135= márùndínlógóje

136= mẹ́rìndínlógóje

137= mẹ́tàdínlógóje

138= méjídínlógóje

139= mọ́kàndínlógóje

140= ogóje

141 = mọ́kànlélógóje

142= méjìlélógóje

143= mẹ́tàlélógóje

144= mẹ́rìnlélógóje

145= márùndínláàdọ́jọ

146= mẹ́rìndínláàdọ́jọ

147= mẹ́tàdínláàdọ́jọ

148= méjídínláàdọ́jọ

149= mọ́kàndínláàdọ́jọ

150= àádọ́jọ

151 = mọ́kànléláàdọ́jọ

152= méjìléláàdọ́jọ

153= mẹ́tàléláàdọ́jọ

154= mẹ́rìnléláàdọ́jọ

155= márùndínlọgọ́jọ

156= mẹ́rìndínlọgọ́jọ

157= mẹ́tàdínlọgọ́jọ

158= méjídínlọgọ́jọ

159= mọ́kàndínlọ́gọ́jọ

160= ọgọ́jọ

161 = mọ́kànlélọ́gọ́jọ

162= méjìlélọ́gọ́jọ

163= mẹ́tàlélọ́gọ́jọ

164= mẹ́rìnlélọ́gọ́jọ

165= márùndínláàdọ́sàn án

166= mẹ́rìndínláàdọ́sàn án

167= mẹ́tàdínláàdọ́sàn án

168= méjídínláàdọ́sàn án

169= mọ́kàndínláàdọ́sàn án

170= àádọ́sàn án

171 = mọ́kànléláàdọ́sàn án

172= méjìléláàdọ́sàn án

173= mẹ́tàléláàdọ́sàn án

174= mẹ́rìnléláàdọ́sàn án

175= márùndínlọ́gọ́sàn án

176= mẹ́rìndínlọ́gọ́sàn án

177= mẹ́tàdínlọ́gọ́sàn án

178= méjídínlọ́gọ́sàn án

179= mọ́kàndínlọ́gọ́sàn án

180= ọgọ́sàn án

181 = mọ́kànlélọ́gọ́sàn án

182= méjìlélọ́gọ́sàn án

183= mẹ́tàlélọ́gọ́sàn án

184= mẹ́rìnlélọ́gọ́sàn án

185= márùndínláàdọ́wàá

186= mẹ́rìndínláàdọ́wàá

187= mẹ́tàdínláàdọ́wàá

188= méjídínláàdọ́wàá

189= mọ́kàndínláàdọ́wàá

190= àádọ́wàá

191 = mọ́kànléláàdọ́wàá

192= méjìléláàdọ́wàá

193= mẹ́tàléláàdọ́wàá

194= mẹ́rìnléláàdọ́wàá

195= márùndínnígba

196= mẹ́rìndínnígba

197= mẹ́tàdínnígba

198= méjídínnígba

199= mọ́kàndínnígba

200= igba

1100 = ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀fà

1200 = ẹgbẹ̀fà

1300 = ẹ̀ẹ́dẹ́gbéje

1400 = egbèje

1500 = ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ

1600 = ẹgbẹ̀jọ

1700 = ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀sán

1800 = ẹgbẹ̀sán

1900 = ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀wàá

2,000 = ẹgbẹ̀wàá/ẹgbàá

201 = mọ́kànlènígba

202= méjìlènígba

203= mẹ́tàlènígba

204= mẹ́rìnlènígba

205= márùndínláàdọ́fà

206= mẹ́rìndínláàdọ́fà

207= mẹ́tàdínláàdọ́fà

208= méjídínláàdọ́fà

209= mọ́kàndínláàdọ́fà

210= àádọ́fà

211 = okòólénígba dín mẹ́san

212= okòólénígba dín mẹjo

213= okòólénígba dín meje

214= okòólénígba dín mẹ́fa

215= okòólénígba dín marun

216= okòólénígba dín mẹ́rìn

217= okòólénígba dín mẹ́tà

218= okòólénígba dín méjí

219= okòólénígba dín kàn

220= okòólénígba

221 = okòólénígba le kan

222 = okòólénígba àti méjí

223 = okòólénígba àti mẹ́tà

224 = okòólénígba àti mẹ́rìn

225 = okòólénígba àti marùn ún

226 = okòólénígba àti mẹ́fà

227 = okòólénígba àti meje

228 = okòólénígba àti mẹjọ

229 = okòólénígba àti mẹsan

230 = okòólénígba àti mẹwàá

231 = òjìlénígba dín mẹ́sàn án

232 = òjìlénígba dín mẹ́jọ

233 = òjìlénígba dín meje

234 = òjìlénígba dín mẹfa

235 = òjìlènígba dín marun

236 = òjìlènígba dín mẹrin

237 = òjìlènígba dín mẹta

238 = òjìlènígba dín meji

239 = òjìlènígba dín ọkan

240 = òjìlénígba / òjìlérúgba

241 = òjìlénígba lé kan

242 = òjìlénígba lé meji

243 = òjìlénígba lé meta

244 = òjìlénígba lé merin

245 = òjìlénígba lé marun

246 = òjìlénígba lé mefa

247 = òjìlénígba lé meje

248 = òjìlénígba lé mejo

249 = òjìlénígba lé mesan

250 = òjìlénígba lé mewaa

251 = ọ̀tàlénígba din mesan

252 = ọ̀tàlénígba din mejo

253 = ọ̀tàlénígba din meje

254 = ọ̀tàlénígba din mefa

255 = ọ̀tàlénígba din marun

256 = ọ̀tàlénígba din merin

257 = ọ̀tàlénígba din meta

258 = ọ̀tàlénígba din meji

259 = ọ̀tàlénígba din kan

260 = ọ̀tàlénígba/ ọ̀tàlérúgba

260 = ọ̀tàlénígba

261 = ọ̀tàlénígba lé kan

262 = ọ̀tàlénígba lé meji

263 = ọ̀tàlénígba lé mẹta

264 = ọ̀tàlénígba lé mẹrin

265 = ọ̀tàlénígba le marun un

266 = ọ̀tàlénígba le mẹfa

267 = ọ̀tàlénígba le meje

268 = ọ̀tàlénígba le mẹjo

269 = ọ̀tàlénígba le mẹsan an

270 = ọ̀tàlénígba le mẹwaa

271 = ọ̀rìnlénígba din mẹsan

272 = ọ̀rìnlénígba din mẹjo

273 = ọ̀rìnlénígba din meje

274 = ọ̀rìnlénígba din mẹfa

275 = ọ̀rìnlénígba din marun

276 = ọ̀rìnlénígba din mẹrin

277 = ọ̀rìnlénígba din mẹta

278 = ọ̀rìnlénígba din meji

279 = ọ̀rìnlénígba din kan

280 = ọ̀rìnlénígba

281 = ọ̀rìnlénígba lé kan

282 = ọ̀rì

283 = ọ̀rìnlénígba lé meta

284 = ọ̀rìnlénígba lé merin

285 = ọ̀rìnlénígba lé marun un

286 = ọ̀rìnlénígba lé mefa

287 = ọ̀rìnlénígba lé meje

288 = ọ̀rìnlénígba lé mejo

289 = ọ̀rìnlénígba lé mesan

290 = ọ̀rìnlénígba lé mewaa

291 = ọ́ọ̀dúnrún dín mesan

292 = ọ́ọ̀dúnrún dín mẹjo

293 = ọ́ọ̀dúnrún dín meje

294 = ọ́ọ̀dúnrún dín mẹfa

295 = ọ́ọ̀dúnrún dín marun un

296 = ọ́ọ̀dúnrún dín mẹrin

297 = ọ́ọ̀dúnrún dín mẹta

298 = ọ́ọ̀dúnrún dín meji

299 = ọ́ọ̀dúnrún dín kan

300 = ọ́ọ̀dúnrún

https://bit.ly/2HWtnBB

Next Page